Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 30 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿قَالُواْ كَذَٰلِكِ قَالَ رَبُّكِۖ إِنَّهُۥ هُوَ ٱلۡحَكِيمُ ٱلۡعَلِيمُ ﴾
[الذَّاريَات: 30]
﴿قالوا كذلك قال ربك إنه هو الحكيم العليم﴾ [الذَّاريَات: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: "Báyẹn ni Olúwa rẹ sọ. Dájúdájú Òun ni Ọlọ́gbọ́n, Onímọ̀ |