Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 38 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَفِي مُوسَىٰٓ إِذۡ أَرۡسَلۡنَٰهُ إِلَىٰ فِرۡعَوۡنَ بِسُلۡطَٰنٖ مُّبِينٖ ﴾
[الذَّاريَات: 38]
﴿وفي موسى إذ أرسلناه إلى فرعون بسلطان مبين﴾ [الذَّاريَات: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àmì tún wà) lára (Ànábì) Mūsā. Nígbà tí A fi ẹ̀rí pọ́nńbélé rán an níṣẹ́ sí Fir‘aon |