Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 60 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿فَوَيۡلٞ لِّلَّذِينَ كَفَرُواْ مِن يَوۡمِهِمُ ٱلَّذِي يُوعَدُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 60]
﴿فويل للذين كفروا من يومهم الذي يوعدون﴾ [الذَّاريَات: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ègbé ni fún àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ ní ọjọ́ wọn tí À ń ṣe ní àdéhùn fún wọn |