Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 44 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿وَإِن يَرَوۡاْ كِسۡفٗا مِّنَ ٱلسَّمَآءِ سَاقِطٗا يَقُولُواْ سَحَابٞ مَّرۡكُومٞ ﴾
[الطُّور: 44]
﴿وإن يروا كسفا من السماء ساقطا يقولوا سحاب مركوم﴾ [الطُّور: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí wọ́n bá sì rí apá kan nínú sánmọ̀ t’ó ya lúlẹ̀, wọ́n á wí pé: "Ẹ̀ṣújò rẹgẹdẹ ni (wọn kò níí gbàgbọ́) |