Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 46 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿يَوۡمَ لَا يُغۡنِي عَنۡهُمۡ كَيۡدُهُمۡ شَيۡـٔٗا وَلَا هُمۡ يُنصَرُونَ ﴾
[الطُّور: 46]
﴿يوم لا يغني عنهم كيدهم شيئا ولا هم ينصرون﴾ [الطُّور: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọjọ́ tí ète wọn kò níí fi kiní kan rọ̀ wọ́n lọ́rọ̀. A ò sì níí ràn wọ́n lọ́wọ́ |