Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 19 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿إِنَّآ أَرۡسَلۡنَا عَلَيۡهِمۡ رِيحٗا صَرۡصَرٗا فِي يَوۡمِ نَحۡسٖ مُّسۡتَمِرّٖ ﴾
[القَمَر: 19]
﴿إنا أرسلنا عليهم ريحا صرصرا في يوم نحس مستمر﴾ [القَمَر: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa rán atẹ́gùn líle sí wọn ní ọjọ́ burúkú kan t’ó ń tẹ̀ síwájú |