Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 18 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿كَذَّبَتۡ عَادٞ فَكَيۡفَ كَانَ عَذَابِي وَنُذُرِ ﴾
[القَمَر: 18]
﴿كذبت عاد فكيف كان عذابي ونذر﴾ [القَمَر: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìran ‘Ād pé òdodo nírọ́. Báwo ni ìyà Mi àti ìkìlọ̀ Mi ti rí ná (lára wọn) |