Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 28 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿وَنَبِّئۡهُمۡ أَنَّ ٱلۡمَآءَ قِسۡمَةُۢ بَيۡنَهُمۡۖ كُلُّ شِرۡبٖ مُّحۡتَضَرٞ ﴾
[القَمَر: 28]
﴿ونبئهم أن الماء قسمة بينهم كل شرب محتضر﴾ [القَمَر: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí o sì fún wọn ní ìró pé dájúdájú pípín ni omi láààrin wọn. Gbogbo ìpín omi sì wà fún ẹni tí ó bá kàn láti wá sí odò |