Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 29 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿فَنَادَوۡاْ صَاحِبَهُمۡ فَتَعَاطَىٰ فَعَقَرَ ﴾
[القَمَر: 29]
﴿فنادوا صاحبهم فتعاطى فعقر﴾ [القَمَر: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà ni wọ́n pe ẹni wọn. Ó wá ọ̀nà láti mú (ràkúnmí náà mọ́lẹ̀). Ó sì pa á |