Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 43 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿أَكُفَّارُكُمۡ خَيۡرٞ مِّنۡ أُوْلَٰٓئِكُمۡ أَمۡ لَكُم بَرَآءَةٞ فِي ٱلزُّبُرِ ﴾
[القَمَر: 43]
﴿أكفاركم خير من أولئكم أم لكم براءة في الزبر﴾ [القَمَر: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé àwọn aláìgbàgbọ́ (nínú) yín l’ó lóore jùlọ sí àwọn wọ̀nyẹn (tí wọ́n ti parẹ́ bọ́ sẹ́yìn) ni tàbí ẹ̀yin ní ìmóríbọ́ kan nínú ìpín-ìpín Tírà (pé ẹ̀yin kò níí jìyà) |