Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 54 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿إِنَّ ٱلۡمُتَّقِينَ فِي جَنَّٰتٖ وَنَهَرٖ ﴾
[القَمَر: 54]
﴿إن المتقين في جنات ونهر﴾ [القَمَر: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) yóò wà nínú àwọn Ọgbà (Ìdẹ̀ra) pẹ̀lú àwọn odò (t’ó ń ṣàn ní ìsàlẹ̀ rẹ̀) |