Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 7 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿وَٱلسَّمَآءَ رَفَعَهَا وَوَضَعَ ٱلۡمِيزَانَ ﴾
[الرَّحمٰن: 7]
﴿والسماء رفعها ووضع الميزان﴾ [الرَّحمٰن: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti sánmọ̀, Allāhu gbé e sókè. Ó sì fi òṣùwọ̀n òfin déédé lélẹ̀ (fún ẹ̀dá) |