Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 79 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿لَّا يَمَسُّهُۥٓ إِلَّا ٱلۡمُطَهَّرُونَ ﴾
[الوَاقِعة: 79]
﴿لا يمسه إلا المطهرون﴾ [الوَاقِعة: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí ẹni tó lè fọwọ́ kàn án (ní ọ̀dọ̀ Allāhu) àfi àwọn ẹni mímọ́ (ìyẹn, àwọn mọlāika) |