Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 127 - الأنعَام - Page - Juz 8
﴿۞ لَهُمۡ دَارُ ٱلسَّلَٰمِ عِندَ رَبِّهِمۡۖ وَهُوَ وَلِيُّهُم بِمَا كَانُواْ يَعۡمَلُونَ ﴾
[الأنعَام: 127]
﴿لهم دار السلام عند ربهم وهو وليهم بما كانوا يعملون﴾ [الأنعَام: 127]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ilé àlàáfíà ń bẹ fun wọn ní ọ̀dọ̀ Olúwa wọn. Òun sì ni Alátìlẹ́yìn wọn nípa ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́ |