×

Dajudaju awon t’o ya esin won si otooto, ti won si di 6:159 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:159) ayat 159 in Yoruba

6:159 Surah Al-An‘am ayat 159 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 159 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ فَرَّقُواْ دِينَهُمۡ وَكَانُواْ شِيَعٗا لَّسۡتَ مِنۡهُمۡ فِي شَيۡءٍۚ إِنَّمَآ أَمۡرُهُمۡ إِلَى ٱللَّهِ ثُمَّ يُنَبِّئُهُم بِمَا كَانُواْ يَفۡعَلُونَ ﴾
[الأنعَام: 159]

Dajudaju awon t’o ya esin won si otooto, ti won si di ijo-ijo, iwo ko ni nnkan kan se po pelu won. Oro won si n be ni odo Allahu. Leyin naa, O maa fun won ni iro ohun ti won n se nise

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إن الذين فرقوا دينهم وكانوا شيعا لست منهم في شيء إنما أمرهم, باللغة اليوربا

﴿إن الذين فرقوا دينهم وكانوا شيعا لست منهم في شيء إنما أمرهم﴾ [الأنعَام: 159]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú àwọn t’ó ya ẹ̀sìn wọn sí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, tí wọ́n sì di ìjọ-ìjọ, ìwọ kò ní n̄ǹkan kan ṣe pọ̀ pẹ̀lú wọn. Ọ̀rọ̀ wọn sì ń bẹ ní ọ̀dọ̀ Allāhu. Lẹ́yìn náà, Ó máa fún wọn ní ìró ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek