Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 2 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿هُوَ ٱلَّذِي خَلَقَكُم مِّن طِينٖ ثُمَّ قَضَىٰٓ أَجَلٗاۖ وَأَجَلٞ مُّسَمًّى عِندَهُۥۖ ثُمَّ أَنتُمۡ تَمۡتَرُونَ ﴾
[الأنعَام: 2]
﴿هو الذي خلقكم من طين ثم قضى أجلا وأجل مسمى عنده ثم﴾ [الأنعَام: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun ni Ẹni tí Ó da yín láti inú erùpẹ̀ amọ̀. Lẹ́yìn náà, Ó fi gbèdéke ìgbà kan sí (ìṣẹ̀mí ayé yín). Àti pé gbèdéké àkókò kan (tún wà fún ayé) lọ́dọ̀ Rẹ̀. Lẹ́yìn náà, ẹ tún ń ṣeyèméjì |