Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 23 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿ثُمَّ لَمۡ تَكُن فِتۡنَتُهُمۡ إِلَّآ أَن قَالُواْ وَٱللَّهِ رَبِّنَا مَا كُنَّا مُشۡرِكِينَ ﴾
[الأنعَام: 23]
﴿ثم لم تكن فتنتهم إلا أن قالوا والله ربنا ما كنا مشركين﴾ [الأنعَام: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, ìfòòró wọn (lórí ìbéèrè náà) kò jẹ́ kiní kan tayọ pé wọ́n á wí pé: “A fi Allāhu, Olúwa wa búra, àwa kì í ṣe ọ̀ṣẹbọ.” |