Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 36 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿۞ إِنَّمَا يَسۡتَجِيبُ ٱلَّذِينَ يَسۡمَعُونَۘ وَٱلۡمَوۡتَىٰ يَبۡعَثُهُمُ ٱللَّهُ ثُمَّ إِلَيۡهِ يُرۡجَعُونَ ﴾
[الأنعَام: 36]
﴿إنما يستجيب الذين يسمعون والموتى يبعثهم الله ثم إليه يرجعون﴾ [الأنعَام: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó ń gbọ́rọ̀ ni àwọn t’ó ń jẹ́pè. Àwọn òkú, Allāhu yó sì gbé wọn dìde. Lẹ́yìn náà, ọ̀dọ̀ Rẹ̀ ni wọn yóò dá wọn padà sí |