×

Ko si ohun abemi kan (t’o n rin) lori ile, tabi eye 6:38 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:38) ayat 38 in Yoruba

6:38 Surah Al-An‘am ayat 38 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 38 - الأنعَام - Page - Juz 7

﴿وَمَا مِن دَآبَّةٖ فِي ٱلۡأَرۡضِ وَلَا طَٰٓئِرٖ يَطِيرُ بِجَنَاحَيۡهِ إِلَّآ أُمَمٌ أَمۡثَالُكُمۚ مَّا فَرَّطۡنَا فِي ٱلۡكِتَٰبِ مِن شَيۡءٖۚ ثُمَّ إِلَىٰ رَبِّهِمۡ يُحۡشَرُونَ ﴾
[الأنعَام: 38]

Ko si ohun abemi kan (t’o n rin) lori ile, tabi eye kan t’o n fo pelu apa re mejeeji bi ko se awon eda kan (bi) iru yin. A ko fi kini kan sile (lai sakosile re) sinu Tira (iyen, ummul-kitab). Leyin naa, odo Oluwa won ni won yoo ko won jo si

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما من دابة في الأرض ولا طائر يطير بجناحيه إلا أمم أمثالكم, باللغة اليوربا

﴿وما من دابة في الأرض ولا طائر يطير بجناحيه إلا أمم أمثالكم﴾ [الأنعَام: 38]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kò sí ohun abẹ̀mí kan (t’ó ń rìn) lórí ilẹ̀, tàbí ẹyẹ kan t’ó ń fò pẹ̀lú apá rẹ̀ méjèèjì bí kò ṣe àwọn ẹ̀dá kan (bí) irú yín. A kò fi kiní kan sílẹ̀ (láì ṣàkọsílẹ̀ rẹ̀) sínú Tírà (ìyẹn, ummul-kitāb). Lẹ́yìn náà, ọ̀dọ̀ Olúwa wọn ni wọn yóò kó wọn jọ sí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek