Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 4 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَمَا تَأۡتِيهِم مِّنۡ ءَايَةٖ مِّنۡ ءَايَٰتِ رَبِّهِمۡ إِلَّا كَانُواْ عَنۡهَا مُعۡرِضِينَ ﴾
[الأنعَام: 4]
﴿وما تأتيهم من آية من آيات ربهم إلا كانوا عنها معرضين﴾ [الأنعَام: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí àmì kan tí ó máa dé bá wọn nínú àwọn àmì Olúwa wọn, àfi kí wọ́n máa gbúnrí kúrò níbẹ̀ |