×

Rara, Oun (nikan) l’e n pe. O si maa mu (inira) ti 6:41 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:41) ayat 41 in Yoruba

6:41 Surah Al-An‘am ayat 41 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 41 - الأنعَام - Page - Juz 7

﴿بَلۡ إِيَّاهُ تَدۡعُونَ فَيَكۡشِفُ مَا تَدۡعُونَ إِلَيۡهِ إِن شَآءَ وَتَنسَوۡنَ مَا تُشۡرِكُونَ ﴾
[الأنعَام: 41]

Rara, Oun (nikan) l’e n pe. O si maa mu (inira) ti e n pe E si kuro (fun yin), ti O ba fe. Eyin yo si gbagbe ohun ti e n fi sebo si I

❮ Previous Next ❯

ترجمة: بل إياه تدعون فيكشف ما تدعون إليه إن شاء وتنسون ما تشركون, باللغة اليوربا

﴿بل إياه تدعون فيكشف ما تدعون إليه إن شاء وتنسون ما تشركون﴾ [الأنعَام: 41]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Rárá, Òun (nìkan) l’ẹ̀ ń pè. Ó sì máa mú (ìnira) tí ẹ̀ ń pè É sí kúrò (fun yín), tí Ó bá fẹ́. Ẹ̀yin yó sì gbàgbé ohun tí ẹ̀ ń fi ṣẹbọ sí I
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek