Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 55 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَكَذَٰلِكَ نُفَصِّلُ ٱلۡأٓيَٰتِ وَلِتَسۡتَبِينَ سَبِيلُ ٱلۡمُجۡرِمِينَ ﴾
[الأنعَام: 55]
﴿وكذلك نفصل الآيات ولتستبين سبيل المجرمين﴾ [الأنعَام: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni A ṣe ń ṣàlàyé àwọn āyah nítorí kí ọ̀nà àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ lè fojú hàn kedere |