Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 66 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَكَذَّبَ بِهِۦ قَوۡمُكَ وَهُوَ ٱلۡحَقُّۚ قُل لَّسۡتُ عَلَيۡكُم بِوَكِيلٖ ﴾
[الأنعَام: 66]
﴿وكذب به قومك وهو الحق قل لست عليكم بوكيل﴾ [الأنعَام: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ènìyàn rẹ pe al-Ƙur’ān nírọ́! (Àmọ́) òdodo ni. Sọ pé: “Èmi kì í ṣe olùṣọ́ lórí yín.” |