Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 67 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿لِّكُلِّ نَبَإٖ مُّسۡتَقَرّٞۚ وَسَوۡفَ تَعۡلَمُونَ ﴾
[الأنعَام: 67]
﴿لكل نبإ مستقر وسوف تعلمون﴾ [الأنعَام: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Gbogbo àsọtẹ́lẹ̀ l’ó ní àkókò (ìṣẹ̀lẹ̀). Láìpẹ́ ẹ máa mọ̀ |