Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 85 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَزَكَرِيَّا وَيَحۡيَىٰ وَعِيسَىٰ وَإِلۡيَاسَۖ كُلّٞ مِّنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[الأنعَام: 85]
﴿وزكريا ويحيى وعيسى وإلياس كل من الصالحين﴾ [الأنعَام: 85]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti (Ànábì) Zakariyyā, Yahyā, ‘Īsā àti ’Ilyās; gbogbo wọn wà nínú àwọn ẹni rere |