×

Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse lati odo 61:13 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah As-saff ⮕ (61:13) ayat 13 in Yoruba

61:13 Surah As-saff ayat 13 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah As-saff ayat 13 - الصَّف - Page - Juz 28

﴿وَأُخۡرَىٰ تُحِبُّونَهَاۖ نَصۡرٞ مِّنَ ٱللَّهِ وَفَتۡحٞ قَرِيبٞۗ وَبَشِّرِ ٱلۡمُؤۡمِنِينَ ﴾
[الصَّف: 13]

Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse lati odo Allahu ati isegun t’o sunmo. Ki o si fun awon onigbagbo ododo ni iro idunnu

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وأخرى تحبونها نصر من الله وفتح قريب وبشر المؤمنين, باللغة اليوربا

﴿وأخرى تحبونها نصر من الله وفتح قريب وبشر المؤمنين﴾ [الصَّف: 13]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àti n̄ǹkan mìíràn tí ẹ tún nífẹ̀ẹ́ sí; (ìyẹn,) àrànṣe láti ọ̀dọ̀ Allāhu àti ìṣẹ́gun t’ó súnmọ́. Kí o sì fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo ní ìró ìdùnnú
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek