Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 18 - المُلك - Page - Juz 29
﴿وَلَقَدۡ كَذَّبَ ٱلَّذِينَ مِن قَبۡلِهِمۡ فَكَيۡفَ كَانَ نَكِيرِ ﴾
[المُلك: 18]
﴿ولقد كذب الذين من قبلهم فكيف كان نكير﴾ [المُلك: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó ṣíwájú wọn kúkú pe òdodo nírọ́. Báwo sì ni bí Mo ṣe (fi ìyà) kọ (aburú fún wọn) ti rí |