Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 42 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَلَا بِقَوۡلِ كَاهِنٖۚ قَلِيلٗا مَّا تَذَكَّرُونَ ﴾
[الحَاقة: 42]
﴿ولا بقول كاهن قليلا ما تذكرون﴾ [الحَاقة: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kì í sì ṣe ọ̀rọ̀ adábigba. Díẹ̀ lẹ̀ ń lò nínú ìrántí |