Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 119 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿فَغُلِبُواْ هُنَالِكَ وَٱنقَلَبُواْ صَٰغِرِينَ ﴾
[الأعرَاف: 119]
﴿فغلبوا هنالك وانقلبوا صاغرين﴾ [الأعرَاف: 119]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A borí wọn níbẹ̀ yẹn. Wọ́n sì darí wálé ní ẹni yẹpẹrẹ |