Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 118 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿فَوَقَعَ ٱلۡحَقُّ وَبَطَلَ مَا كَانُواْ يَعۡمَلُونَ ﴾
[الأعرَاف: 118]
﴿فوقع الحق وبطل ما كانوا يعملون﴾ [الأعرَاف: 118]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, òdodo dé. Ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́ sì bàjẹ́ |