Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 80 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿وَلُوطًا إِذۡ قَالَ لِقَوۡمِهِۦٓ أَتَأۡتُونَ ٱلۡفَٰحِشَةَ مَا سَبَقَكُم بِهَا مِنۡ أَحَدٖ مِّنَ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الأعرَاف: 80]
﴿ولوطا إذ قال لقومه أتأتون الفاحشة ما سبقكم بها من أحد من﴾ [الأعرَاف: 80]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí Ànábì) Lūt, nígbà tí ó sọ fún ìjọ rẹ̀ pé: "Ṣé ẹ óò máa ṣe ìbàjẹ́ ni tí kò sí ẹnì kan nínú àwọn ẹ̀dá t’ó ṣe irú rẹ̀ rí |