Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 10 - الجِن - Page - Juz 29
﴿وَأَنَّا لَا نَدۡرِيٓ أَشَرٌّ أُرِيدَ بِمَن فِي ٱلۡأَرۡضِ أَمۡ أَرَادَ بِهِمۡ رَبُّهُمۡ رَشَدٗا ﴾
[الجِن: 10]
﴿وأنا لا ندري أشر أريد بمن في الأرض أم أراد بهم ربهم﴾ [الجِن: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwa kò sì mọ̀ bóyá aburú ni wọ́n gbà lérò pẹ̀lú àwọn t’ó wà lórí ilẹ̀ tàbí Olúwa wọn gbèrò ìmọ̀nà fún wọn |