×

Dajudaju nigba ti a gbo nipa imona (lati inu al-Ƙur’an), a gba 72:13 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Jinn ⮕ (72:13) ayat 13 in Yoruba

72:13 Surah Al-Jinn ayat 13 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jinn ayat 13 - الجِن - Page - Juz 29

﴿وَأَنَّا لَمَّا سَمِعۡنَا ٱلۡهُدَىٰٓ ءَامَنَّا بِهِۦۖ فَمَن يُؤۡمِنۢ بِرَبِّهِۦ فَلَا يَخَافُ بَخۡسٗا وَلَا رَهَقٗا ﴾
[الجِن: 13]

Dajudaju nigba ti a gbo nipa imona (lati inu al-Ƙur’an), a gba a gbo. Nitori naa, enikeni ti o ba gba Oluwa re gbo, ki o ma beru adinku (esan rere) ati (alekun) aburu

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وأنا لما سمعنا الهدى آمنا به فمن يؤمن بربه فلا يخاف بخسا, باللغة اليوربا

﴿وأنا لما سمعنا الهدى آمنا به فمن يؤمن بربه فلا يخاف بخسا﴾ [الجِن: 13]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú nígbà tí a gbọ́ nípa ìmọ̀nà (láti inú al-Ƙur’ān), a gbà á gbọ́. Nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá gba Olúwa rẹ̀ gbọ́, kí ó má bẹ̀rù àdínkù (ẹ̀san rere) àti (àlékún) aburú
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek