Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qiyamah ayat 38 - القِيَامة - Page - Juz 29
﴿ثُمَّ كَانَ عَلَقَةٗ فَخَلَقَ فَسَوَّىٰ ﴾
[القِيَامة: 38]
﴿ثم كان علقة فخلق فسوى﴾ [القِيَامة: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, ó di ẹ̀jẹ̀ dídì. (Allāhu) sì ṣẹ̀dá (rẹ̀). Ó sì ṣe é t’ó dọ́gba jálẹ̀ léèyàn |