×

Aso ara won ni aso aran felefele alawo eweko ati aso alagbaaa. 76:21 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Insan ⮕ (76:21) ayat 21 in Yoruba

76:21 Surah Al-Insan ayat 21 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Insan ayat 21 - الإنسَان - Page - Juz 29

﴿عَٰلِيَهُمۡ ثِيَابُ سُندُسٍ خُضۡرٞ وَإِسۡتَبۡرَقٞۖ وَحُلُّوٓاْ أَسَاوِرَ مِن فِضَّةٖ وَسَقَىٰهُمۡ رَبُّهُمۡ شَرَابٗا طَهُورًا ﴾
[الإنسَان: 21]

Aso ara won ni aso aran felefele alawo eweko ati aso alagbaaa. A si maa fi egba-owo onifadaka se won ni oso. Oluwa won yo si fun won ni ohun mimu mimo mu

❮ Previous Next ❯

ترجمة: عاليهم ثياب سندس خضر وإستبرق وحلوا أساور من فضة وسقاهم ربهم شرابا, باللغة اليوربا

﴿عاليهم ثياب سندس خضر وإستبرق وحلوا أساور من فضة وسقاهم ربهم شرابا﴾ [الإنسَان: 21]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Aṣọ ara wọn ni aṣọ àrán fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ aláwọ̀ ewéko àti aṣọ alágbàáà. A sì máa fi ẹ̀gbà-ọwọ́ onífàdákà ṣe wọ́n ní ọ̀ṣọ́. Olúwa wọn yó sì fún wọn ní ohun mímu mímọ́ mu
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek