Quran with Yoruba translation - Surah Al-Insan ayat 5 - الإنسَان - Page - Juz 29
﴿إِنَّ ٱلۡأَبۡرَارَ يَشۡرَبُونَ مِن كَأۡسٖ كَانَ مِزَاجُهَا كَافُورًا ﴾
[الإنسَان: 5]
﴿إن الأبرار يشربون من كأس كان مزاجها كافورا﴾ [الإنسَان: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn ẹni rere, wọn yóò máa mu omi kan nínú ife. Ohun tí A pòpọ̀ mọ́ (omi náà) ni káfúrà |