Quran with Yoruba translation - Surah Al-Insan ayat 6 - الإنسَان - Page - Juz 29
﴿عَيۡنٗا يَشۡرَبُ بِهَا عِبَادُ ٱللَّهِ يُفَجِّرُونَهَا تَفۡجِيرٗا ﴾
[الإنسَان: 6]
﴿عينا يشرب بها عباد الله يفجرونها تفجيرا﴾ [الإنسَان: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Omi ìṣẹ́lẹ̀rú kan ni, tí àwọn ẹrúsìn Allāhu yóò máa mu, tí wọn yó sì máa mú un ṣàn jáde dáadáa (sí ibi tí wọ́n bá fẹ́) |