Quran with Yoruba translation - Surah An-Naba’ ayat 37 - النَّبَإ - Page - Juz 30
﴿رَّبِّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَمَا بَيۡنَهُمَا ٱلرَّحۡمَٰنِۖ لَا يَمۡلِكُونَ مِنۡهُ خِطَابٗا ﴾
[النَّبَإ: 37]
﴿رب السموات والأرض وما بينهما الرحمن لا يملكون منه خطابا﴾ [النَّبَإ: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹsan náà wá láti ọ̀dọ̀) Olúwa àwọn sánmọ̀, ilẹ̀ àti ohun t’ó wà láààrin méjèèjì, Àjọkẹ́-ayé. Wọn kò sì ní ìkápá ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ Rẹ̀ |