Quran with Yoruba translation - Surah ‘Abasa ayat 19 - عَبَسَ - Page - Juz 30
﴿مِن نُّطۡفَةٍ خَلَقَهُۥ فَقَدَّرَهُۥ ﴾
[عَبَسَ: 19]
﴿من نطفة خلقه فقدره﴾ [عَبَسَ: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nínú àtọ̀ l’Ó ti ṣẹ̀dá rẹ̀. Ó sì pèbùbù (ẹ̀yà-ara) rẹ̀ |