Quran with Yoruba translation - Surah Al-InfiTar ayat 6 - الانفِطَار - Page - Juz 30
﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلۡإِنسَٰنُ مَا غَرَّكَ بِرَبِّكَ ٱلۡكَرِيمِ ﴾
[الانفِطَار: 6]
﴿ياأيها الإنسان ما غرك بربك الكريم﴾ [الانفِطَار: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ ènìyàn, kí ni ó tàn ọ́ jẹ nípa Olúwa rẹ, Alápọ̀n-ọ́nlé |