Quran with Yoruba translation - Surah Al-InfiTar ayat 5 - الانفِطَار - Page - Juz 30
﴿عَلِمَتۡ نَفۡسٞ مَّا قَدَّمَتۡ وَأَخَّرَتۡ ﴾
[الانفِطَار: 5]
﴿علمت نفس ما قدمت وأخرت﴾ [الانفِطَار: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (nígbà náà ni) ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan yóò mọ ohun tí ó tì síwájú (nínú iṣẹ́ rẹ̀) àti ohun tí ó fi sẹ́yìn (nínú orípa iṣẹ́ rẹ̀) |