Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 126 - التوبَة - Page - Juz 11
﴿أَوَلَا يَرَوۡنَ أَنَّهُمۡ يُفۡتَنُونَ فِي كُلِّ عَامٖ مَّرَّةً أَوۡ مَرَّتَيۡنِ ثُمَّ لَا يَتُوبُونَ وَلَا هُمۡ يَذَّكَّرُونَ ﴾
[التوبَة: 126]
﴿أو لا يرون أنهم يفتنون في كل عام مرة أو مرتين ثم﴾ [التوبَة: 126]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé wọn kò rí i pé À ń dán wọn wò ní ẹ̀ẹ̀ kan tàbí ẹ̀ẹ̀ méjì ní ọdọọdún. Lẹ́yìn náà, wọn kò ronú pìwàdà, wọn kò sì lo ìrántí |