×

Eni ti o maa samojuto awon mosalasi Allahu ni eni t’o gbagbo 9:18 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah At-Taubah ⮕ (9:18) ayat 18 in Yoruba

9:18 Surah At-Taubah ayat 18 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah At-Taubah ayat 18 - التوبَة - Page - Juz 10

﴿إِنَّمَا يَعۡمُرُ مَسَٰجِدَ ٱللَّهِ مَنۡ ءَامَنَ بِٱللَّهِ وَٱلۡيَوۡمِ ٱلۡأٓخِرِ وَأَقَامَ ٱلصَّلَوٰةَ وَءَاتَى ٱلزَّكَوٰةَ وَلَمۡ يَخۡشَ إِلَّا ٱللَّهَۖ فَعَسَىٰٓ أُوْلَٰٓئِكَ أَن يَكُونُواْ مِنَ ٱلۡمُهۡتَدِينَ ﴾
[التوبَة: 18]

Eni ti o maa samojuto awon mosalasi Allahu ni eni t’o gbagbo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin, t’o si n kirun, t’o n yo Zakah, ko si paya (orisa kan) leyin Allahu. Awon wonyen ni won kuku wa ninu awon olumona

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إنما يعمر مساجد الله من آمن بالله واليوم الآخر وأقام الصلاة وآتى, باللغة اليوربا

﴿إنما يعمر مساجد الله من آمن بالله واليوم الآخر وأقام الصلاة وآتى﴾ [التوبَة: 18]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ẹni tí ó máa ṣàmójútó àwọn mọ́sálásí Allāhu ni ẹni t’ó gbàgbọ́ nínú Allāhu àti Ọjọ́ Ìkẹ́yìn, t’ó sì ń kírun, t’ó ń yọ Zakāh, kò sì páyà (òrìṣà kan) lẹ́yìn Allāhu. Àwọn wọ̀nyẹn ni wọ́n kúkú wà nínú àwọn olùmọ̀nà
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek