Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Alaq ayat 13 - العَلَق - Page - Juz 30
﴿أَرَءَيۡتَ إِن كَذَّبَ وَتَوَلَّىٰٓ ﴾
[العَلَق: 13]
﴿أرأيت إن كذب وتولى﴾ [العَلَق: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ fún mi (nípa ìyà rẹ̀) tí ó bá jẹ́ pé ó pe òdodo nírọ́, tí ó sì kẹ̀yìn sí i |