Quran with Yoruba translation - Surah Al-Bayyinah ayat 7 - البَينَة - Page - Juz 30
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ أُوْلَٰٓئِكَ هُمۡ خَيۡرُ ٱلۡبَرِيَّةِ ﴾
[البَينَة: 7]
﴿إن الذين آمنوا وعملوا الصالحات أولئك هم خير البرية﴾ [البَينَة: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo (ìyẹn, àwọn mùsùlùmí), tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere, àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni ẹ̀dá t’ó dára jùlọ |