Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 67 - يُونس - Page - Juz 11
﴿هُوَ ٱلَّذِي جَعَلَ لَكُمُ ٱلَّيۡلَ لِتَسۡكُنُواْ فِيهِ وَٱلنَّهَارَ مُبۡصِرًاۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَأٓيَٰتٖ لِّقَوۡمٖ يَسۡمَعُونَ ﴾
[يُونس: 67]
﴿هو الذي جعل لكم الليل لتسكنوا فيه والنهار مبصرا إن في ذلك﴾ [يُونس: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun ni Ẹni t’Ó ṣe òru fun yín nítorí kí ẹ lè sinmi nínú rẹ̀. (Ó ṣe) ọ̀sán ní (àsìkò) tí ẹ óò ríran (kedere). Dájúdájú àwọn àmì wà nínú ìyẹn fún ìjọ t’ó ń gbọ́rọ̀ (òdodo) |