Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 69 - يُونس - Page - Juz 11
﴿قُلۡ إِنَّ ٱلَّذِينَ يَفۡتَرُونَ عَلَى ٱللَّهِ ٱلۡكَذِبَ لَا يُفۡلِحُونَ ﴾
[يُونس: 69]
﴿قل إن الذين يفترون على الله الكذب لا يفلحون﴾ [يُونس: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Dájúdájú àwọn t’ó ń dá àdápa irọ́ mọ́ Allāhu, wọn kò níí jèrè.” |