Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 79 - يُونس - Page - Juz 11
﴿وَقَالَ فِرۡعَوۡنُ ٱئۡتُونِي بِكُلِّ سَٰحِرٍ عَلِيمٖ ﴾
[يُونس: 79]
﴿وقال فرعون ائتوني بكل ساحر عليم﴾ [يُونس: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fir‘aon wí pé: “Ẹ lọ mú gbogbo àwọn onímọ̀ nípa idán pípa wá fún mi.” |