Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 80 - يُونس - Page - Juz 11
﴿فَلَمَّا جَآءَ ٱلسَّحَرَةُ قَالَ لَهُم مُّوسَىٰٓ أَلۡقُواْ مَآ أَنتُم مُّلۡقُونَ ﴾
[يُونس: 80]
﴿فلما جاء السحرة قال لهم موسى ألقوا ما أنتم ملقون﴾ [يُونس: 80]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí àwọn òpìdán sì dé, (Ànábì) Mūsā sọ fún wọn pé: “Ẹ ju ohun tí ẹ máa jù sílẹ̀.” |