Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 121 - هُود - Page - Juz 12
﴿وَقُل لِّلَّذِينَ لَا يُؤۡمِنُونَ ٱعۡمَلُواْ عَلَىٰ مَكَانَتِكُمۡ إِنَّا عَٰمِلُونَ ﴾
[هُود: 121]
﴿وقل للذين لا يؤمنون اعملوا على مكانتكم إنا عاملون﴾ [هُود: 121]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí o sì sọ fún àwọn tí kò gbàgbọ́ pé: "Ẹ máa ṣe bí ẹ ti fẹ́ nínú ẹ̀sìn yín. Dájúdájú àwa náà yóò máa bá ẹ̀sìn wa lọ |